Egbe PDP Ti JAWE OLUBORI NI IPINLE OYO -ISIAKA FATOKUN LO SO BE

Bi o ti wu ki ori egbe wa ni yio wole ni gbogbo ijoba ibile metetalelognon to wa ni ipinle oyo,Alh Isiaka Fatokun lo so oro yi pelu awon akoroyin wa ni nigba ti eto ibo didi fun alaga ati kanselo nlo lowo ni ipinle naa.
Alh Isiaka lo soro yi wipe ise ti onimoero Seyi makinde ti se ni ipinle Oyo ti se okunfa ki gbogbo omo egbe PDP ti o ndije si ipo alaga tabi kansilo ki o gbe igba oroke ninu idibo naa. 

Alh Isiaka ti se alaga egbe PDP ni ijoba ibile ibadan northeast,so wipe lati ojo ti ibo ti nwaye ni ipinle Oyo oun ko ti ri  idibo ti ko ni jagidijagan tabi sise ara eni ni ijamba tabi pipa ara eni bi eto idibo yi,ibo ti o lo nirowo irose bi toni ko si iru re ni Nigeria,ki gomina fi aye gba gbogbo egbe, ki ibo naa si tun ri bi o se ri yi,o ni ko sele ri,

Alh Isiaka so ninu oro re pe ajo ti o nri si eto ibido ni ipinle Oyo  naa mu ileri won se,pe won ko ni fi aye mogomogo sile fun egbe kankan  lati ba ajo eleto idibo naa je.

Owa dupe lowo gbogbo oludibo  jagejado ipinle Oyo pe won mo oore o ,tori iru asiko bayi ni a won mo nmo ijoba ti o se daada si ara ilu,be lo si tun gbe osuba bamba fun  ololajulo Gomina onimo ero Seyi Makinde fun ise takuntakun ti won ni ipinle Oyo.

No comments

Powered by Blogger.