Ijoba Ibile Afijio Yio Se Takuntakun Ju Ti Tateyin wa Lo-Hon Akindele Lo so be

Hon Sunday Akindele Ojo ti o je alaga ijoba ibile afijio,lo fonrere yi pe ki gbogbo omo ijoba ibile afijio ma reti igba otun ni ijoba ibile naa.

Alaga so oro yi nibi iforowanilenu wo pelu awon akoroyin wa (oduduwawatch) ni gbongan ile ise ijo ibile afijio,oloye Sunday fipe,niwon igba ti olorun ti tun fun awon ni ore-ofe lati dibo wole gege bi alaga ijoba ibile naa,pe odidandan fun awon lati tele ilana ti olola julo Gomina Oluwaseyi Makinde ti pe kale ni ipinle Oyo.
Emi koni salai ye so,Pe Gomina Seyi Amakinde je eniti ti olorun ran siwa ni ipinle Oyo,ti won si ti se opolopo ise lati so ipinle di otun.

Oloye Sunday wipe oun naa yio sa gbogbo ipa lati mu ijoba ibile Afijio de ile ileri.

Hon.Sunday wipe laipe ijoba oun yio bere ise lori eto ilera,sise onigbowo fun awon agbe,eto eko,eto abo, ati sise iranlowo fun awon odo.koda ani eto fun ere idara lokan ojokan fun awon odo ati awon omo ile eko.

Oloye Sunday Akindele wa dupe Pataki lowo Gomina ipinle Oyo fun ifowosowopo won pelu gbogbo ijoba ibile Oyo.
Awon ona ti angba lati mu owo si apo ijoba,gbogbo awon ero pakopako ati ero katakata ti awon agbe ma nfi kole, ti o ti baje ni ijoba oun ti bere si se atunse re,ki o ma ba si idaduro kankan fun awon agbe,beni awon ti won fi tun ona se,ni awon ti se atunse re.

Hon. Sunday wipe laipe eto gbigba awon osise si enu ise oba yio to bere leyi ti awon yio gba opolopo awon osise si ijoba ibile yi.

No comments

Powered by Blogger.