Ooni Je Angeli Ti Olorun Ran Si Iran Yoruba-AberuagbaNinu gbogbo oba alade ni ile karo ojire,arole Oodua ti gbogbo aye mo ni Ooni je akoko ninu awon oba,won atile mape ni oba Olori aye gbogbo Ooni adimula nife.
     
 Opolopo oba lo ti je nile Ife laimoye egbelegbe odun seyin,sugbon oba Enitan Ogunwusi ojaja ll je okan lara awon Angeli to gbe awo eniyan wo ti o si nse isetakuntakun ti olorun fi ran,lati igba ti oba yi ti gun ori ite baba re ni iyato ti ba ohun gbogbo nile yoruba.
 
 Ni akoko, iwa irele re mu ki opolopo oba onigberaga nile yoruba ko
ogbon,kikonimora re ti yi oye ati iwa awon oba miran lokan pada,besi ni wiwa ona abayo fun awon odo ni gbogbo ile yoruba ki je oba ogunwusi o sun,ojojumo ni oba nronu igbagba soke Omo oduduwa.
 
 Ni bi osukan ati abo sehin ni arun kan seyo ni gbogbo agbaye larin alawo funfun ati eniyan dudu,bi arun naa se npa gigun lo npa eni kikuru,ti awon ojogbon nse iwadi ona abayo si arun naa ti won ko ti ri ona abayo.
   
Ninu aisun ati aiwo kabiesi ogunwusi Ooni ti ile Ife se asaro ninu okan re pe bi awon oyinbo alawo funfun ko ba ti ri ona abayo ki abi awon alale lere ti oba so wipe agbo ati awon nka to gbona la o fi ma dena arun na ti a o si ma fo owo wa dede lorekore,ninu asaro kabiesi ni won ti ro pe ki awon se eto ero mojele apakokoro arun ori ile, iyen (fumigating machine) ti won si pin kakakiri ipinle gbogbo ni ile yoruba leyi ti iru re koti waye ri pelu oba alade kankan.
Eyi ni emi Kunle alayo omoaberuagba ri ti mo se te akojade yi sita pe ki olorun olodunmare bawa fi alafia ati emigigun ta oba wa lore,gbogbo erongba oba Enitan lori Iran yoruba yio wa si imuse.aberuagba wipe Angeli oluwa ni Ooni ogunwusi.
Gbogbo odo ni ile kaaro oojire ki afi owosopo pelu kabiesi.iba 

No comments

Powered by Blogger.