Aalafin Oyo Ti Waja

Kabiesi Oba Dr Lamidi Adeyemi  lll,ladigbolu Aalafin ti teri gbaso loru ana lehin aisan ranpe,

Je kin lo re se ayewo ara ni oba lamidi se lo si ile iwosan Afe babalola nipinle ekiti ki alimutu to se abewo si iku baba yeye alase ikeji awon orisa,awon dokita gba gbogbo igbiyanju lati ri pe awon do ju ti alimutu sugbon aisan laawo a ki ri tolojo se.

Laro yi ni agbenuso Aalafin lori eto iroyin iyen Ogbeni Bode Durojaye fito okan lara awon akoroyin Oduduwa watch leti  pe looto ni Aalafin ti waja o,ti o si wipe bi gbogbo eto yio se ma lo ni awon yio tun ma je ki omo naijiria ma gbo o.
 E teti leko fun awon akotun iroyin to tun kan laipe 

No comments

Powered by Blogger.