Amofin Victoria Irabor Se Ifilole Iwe Akosile Re

Loni ti se ojo kerinlelogun osu Karun Odun 2023 ni amofin Victoria Anwuli Irabor ti se iyawo Oga awon omoogun orileede Nigeria ati Aare Egbe awon iyawo awon ologun lorile ede yi ,se Ifilole Iwe kan ti a pe akole re ni irinajo  iyawo Awon omo Ologun lorileede yi .ekunrere iroyin na yio waye laipe 

No comments

Powered by Blogger.